Sáàmù 18:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi òkùnkùn ṣe ibojì Rẹ̀, ó fi ṣe ìbòrí yí ara Rẹ̀ kákùrúkùrù òjò dúdú ní ojú ọ̀run.

Sáàmù 18

Sáàmù 18:5-15