Sáàmù 17:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ti dán àyà mi wò, ìwọ sì yẹ̀ mí wò ní òru.Bí ìwọ bá dán mi wò, ìwọ kì yóò rí ohunkóhunèmi ti pinnu pé ẹnu mi kì yóò ṣẹ̀.

Sáàmù 17

Sáàmù 17:1-9