Sáàmù 17:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Olúwa, nípa ọwọ́ Rẹ gbà mí kúrò lọ́wọ́ irú àwọn ènìyàn bẹ́ẹ̀,kúrò lọ́wọ́ àwọn ènìyàn ayé yìí, tí èrè wọn wà nínú ayé yìí;Ìwọ ń pa ebi àwọn tí ìwọ fẹ́ràn lẹ́nu mọ́;àwọn ọmọ wọn sì ní ọ̀pọ̀lọpọ̀,wọ́n sì kó ọrọ̀ jọ fún àwọn ọmọ wọn.