Sáàmù 16:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìṣòro àwọn wọ̀n ọn nì yóò pọ̀ síiàwọn tí ń tọ ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn.Ẹbọ ohun mímu ẹ̀jẹ̀ wọn ni èmi kì yóò ta sílẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni èmi kì yóò dá orúkọ wọn lẹ́nu mi.

Sáàmù 16

Sáàmù 16:1-5