Sáàmù 16:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sọ fún Olúwa, “ìwọ ni Ọlọ́run mi,lẹ́yìn Rẹ èmi kò ní ire kan.”

Sáàmù 16

Sáàmù 16:1-11