Sáàmù 150:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.Ẹ fi ìyìn fún Ọlọ́run ní ibi mímọ́ Rẹ̀Ẹ yìn ín nínú agbára ọ̀run Rẹ̀.

2. Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ agbára Rẹ̀.Ẹ yìn ín fún títóbi Rẹ̀ tí ó tayọ̀.

Sáàmù 150