Sáàmù 149:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti fi ẹ̀wọ̀n de àwọn ọba wọnàti láti fi ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀irin de àwọn ọlọ́lá wọn.

Sáàmù 149

Sáàmù 149:7-9