Sáàmù 149:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí Ísírẹ́lì kí ó ní inú dídùn sí ẹni tí ó dá ajẹ́ kí àwọn ọmọ Síónì kí ó níayọ̀ nínú ọba wọn.

Sáàmù 149

Sáàmù 149:1-3