Sáàmù 148:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fi ìyìn fún un,gbogbo ẹ̀yin ángẹ́lì Rẹ̀Ẹ fi ìyìn fún un,gbogbo ẹ̀yin ọmọ ogun Rẹ̀

Sáàmù 148

Sáàmù 148:1-11