Sáàmù 147:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun kó tí ṣe irú èyí sí orílẹ̀ èdè kan rí, Bí ó ṣe ti ìdájọ́ Rẹ̀wọn ko mọ òfin Rẹ̀.Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Sáàmù 147

Sáàmù 147:16-20