Sáàmù 146:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayéòkun àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú wọn Olúwa, tí ó pa òtítọ́ mọ́ títí láéláé

Sáàmù 146

Sáàmù 146:1-10