Sáàmù 145:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu mi yóò sọ̀rọ̀ ìyìn Olúwa.Jẹ́ kí gbogbo ẹ̀dá yín orúkọ Rẹ̀ mímọ́ láé àti láéláé.

Sáàmù 145

Sáàmù 145:18-21