Sáàmù 144:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún àwọn ènìyàn náàtí ó wà ní irú ipò bẹ́ẹ̀, Ayọ̀ ni fún àwọntí ẹni ti Ọlọ́run Olúwa ń ṣe.

Sáàmù 144

Sáàmù 144:6-15