Sáàmù 143:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọ́ mi láti ṣe ìfẹ́ Rẹ,nítorí ìwọ ni Ọlọ́run mijẹ́ kí ẹ̀mí Rẹ dídáradarí mi sí ilẹ̀ tí ó tẹ́jú.

Sáàmù 143

Sáàmù 143:3-12