Sáàmù 141:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe jẹ́ kí ọkàn mi fà sí ohun tí ń ṣe ibi,Láti máa bá àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ búburúmá sì ṣe jẹ́ kí èmi jẹ́ àdídùn wọn.

Sáàmù 141

Sáàmù 141:1-10