Sáàmù 140:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́ àwọn olódodo yóòmáa fi ọpẹ́ fún orúkọ Rẹ;àwọn ẹni dídúró ṣinṣin yóò máa gbé iwájú Rẹ.

Sáàmù 140

Sáàmù 140:4-13