Ìgbàlà àwọn Ísírẹ́lì yóò ti Síónì wá!Nígbà tí Olúwa bá mú ìkólọ àwọn ènìyàn Rẹ̀ padà,jẹ́ kí Jákọ́bù kí ó yọ̀, kí inú Ísírẹ́lì kí ó dùn!