Asiwèrè wí nínú ọkàn Rẹ̀ pé,“kò sí Ọlọ́run.”Wọ́n díbàjẹ́, iṣẹ́ wọn sì burú;kò sí ẹnìkan tí ó ṣe rere.