Sáàmù 139:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo ní èmi yóò gbé lọ kúrò ní ọwọ́ ẹ̀mí Rẹ?Tàbí níbo ní èmi yóò sáré kúrò níwájú Rẹ?

Sáàmù 139

Sáàmù 139:3-17