Sáàmù 139:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú Rẹ̀ ti rí ohun ara mi tí ó wà láìpé:àti nínú ìwé Rẹ ni a ti kọ gbogbo wọn sí,ní ojojumọ́ ni a ń dá wọn,nígbà tí ọ̀kan wọn kò tí i sí.

Sáàmù 139

Sáàmù 139:14-17