Sáàmù 139:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo bá wí pé, ǹjẹ́ kí òkùnkùn kí ó bò mí mọ́lẹ̀;kí ìmọ́lẹ̀ kí ó di òru yí mi ká.

Sáàmù 139

Sáàmù 139:9-16