Sáàmù 139:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, ìwọ tí wádìí mi,ìwọ sì ti mọ̀ mí.

2. Ìwọ mọ̀ ìjòkòó mi àti ìdìde mi,ìwọ mọ̀ ìrò mi ní ọ̀nà jnijin réré.

3. Ìwọ yí ipa ọ̀nà mi kán àti idùbúlẹ̀ mi,gbogbo ọ̀nà mi sì di mímọ̀ fún ọ.

Sáàmù 139