Sáàmù 138:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí èmi tilẹ̀ ń rìn nínú ìpọ́njú ìwọ ni yóò sọ mi di àyè;ìwọ ó nà ọwọ́ Rẹ̀ si àwọn ọ̀tá mi,ọwọ́ ọ̀tún Rẹ yóò sì gbà mí.

Sáàmù 138

Sáàmù 138:4-8