Sáàmù 138:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó máa gbàdúrà sí ìhà tẹ́ḿpìlì mímọ́ Rẹ̀èmi ó sì máa yin orúkọ Rẹnítorí ìṣeun ìfẹ́ Rẹ àti òtítọ́ Rẹ;nítorí ìwọ gbé ọ̀rọ̀ Rẹ ga ju orúkọ Rẹ lọ.

Sáàmù 138

Sáàmù 138:1-4