Sáàmù 135:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú ìkuku góke láti òpin ilẹ̀ wá:ó dá mọ̀nàmọ́ná fún òjo:ó ń mú afẹ́fé ti inú ilẹ̀ ìṣúra Rẹ̀ wá.

Sáàmù 135

Sáàmù 135:1-16