Sáàmù 135:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin ara ilé Ísírẹ́lì, ẹ fi ìbùkún fún Olúwa,ẹ̀yin ará ilé Árónì, fi ìbùkún fún Olúwa.

Sáàmù 135

Sáàmù 135:18-21