Sáàmù 133:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dàbí òróró ìkúnra iyebíye ní orí,tí ó ṣàn dé irungbọ̀n, àní irungbọ̀n Árónì:tí ó sì ṣàn sí etí aṣọ sórí Rẹ̀;

Sáàmù 133

Sáàmù 133:1-3