Sáàmù 132:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí a fi òdodo wọ àwọn àlùfáà Rẹ:kí àwọn ènìyàn mímọ́ Rẹ kí ó máa hó fún ayọ̀.

Sáàmù 132

Sáàmù 132:4-16