Sáàmù 132:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọ̀tá Rẹ̀ ni èmi yóò fi ìtìjú wọ̀:ṣùgbọ́n lára Òun tìkararẹ̀ ni adé yóò máa gbilẹ̀.

Sáàmù 132

Sáàmù 132:10-18