Sáàmù 132:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ní ibi ìsinmi mí láéláé:níhìn-ín ni èmi yóò máa gbé:nítorí tí mo fẹ́ ẹ.

Sáàmù 132

Sáàmù 132:9-15