Sáàmù 132:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọn ọmọ Rẹ̀ yóò bá pa májẹ̀mú mi mọ́àti ẹ̀rí mi tí èmi yóò kọ́ wọn,àwọn ọmọ wọn pẹ̀lú yóò jókoo lórí ìtẹ́ Rẹ láéláé.

Sáàmù 132

Sáàmù 132:4-17