Sáàmù 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò ti pẹ́ tó tí èmi ó máa bá èrò mi jà,àti ní ojojúmọ́ ni èmi ń ní ìbànújẹ́ ní ọkàn mi?Yóò ti pẹ́tó tí àwọn ọ̀ta mi yóò máa borí mi?

Sáàmù 13

Sáàmù 13:1-3