Sáàmù 129:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Kí wọn kí ó dàbí koríko orí ilẹ̀tí ó gbẹ dànù kí o tó dàgbà sókè:

7. Èyí tí olóko pípa kó kún ọwọ́ Rẹ̀:bẹ́ẹ̀ ní ẹni tí ń di ìtì, kó kún apá Rẹ̀.

8. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn tí ń kọjá lọ kó wí pé,ìbùkún Olúwa kí o pẹ̀lú yín:àwa ń súre fún yin ní orúkọ Olúwa.

Sáàmù 129