Sáàmù 129:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí gbogbo àwọn tí ó korìíra Síónì kí ó dààmú,kí wọn kí ó sì yí ẹ̀yìn padà.

Sáàmù 129

Sáàmù 129:1-8