Sáàmù 129:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójúláti ìgbà èwe mi wá;ṣíbẹ̀ wọn kò tíì borí mi.

Sáàmù 129

Sáàmù 129:1-7