Sáàmù 123:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyèsí, bí ojú àwọnìránṣẹ́ kùnrin ti máa ń wo ọwọ́ àwọn baba wọn,àti bí ojú ìránṣẹ́-bìnrin ti máa ń wo ọwọ́ ìyá Rẹ̀bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo Olúwa Ọlọ́run wa,títí yóò fi ṣàánú fún wa.

Sáàmù 123

Sáàmù 123:1-4