Sáàmù 122:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbi tí àwọn ẹ̀yà máa ń gòkè lọ,àwọn ẹ̀yà Olúwa,ẹ̀rí fún Ísírẹ́lì, látimáa dúpẹ́ fún orúkọ Olúwa.

Sáàmù 122

Sáàmù 122:1-9