Sáàmù 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ Olúwa sì jẹ aláìlábùkù,gẹ́gẹ́ bí fàdákà ti a yọ́ nínú ìléru àmọ́,tí a sọ di mímọ́ nígbà méje.

Sáàmù 12

Sáàmù 12:1-7