Sáàmù 119:99 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ní iyè ińu ju gbogbo olùkọ́ mi lọ,nítorí èmi ń ṣe àṣàrò nínú òfin Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:89-107