Sáàmù 119:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn agbéraga fi mi ṣe ẹlẹ́yà láì dádúró,ṣùgbọ́n èmi kò padà nínú òfin Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:44-55