Sáàmù 119:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún mi ní òye, èmi yóò sì pa òfin Rẹ mọ́èmi yóò sì máa kíyèsíi pẹ̀lú ọkàn mi.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:26-43