Sáàmù 119:161 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn alákòóso ṣe inúnibíni sí mi láìnídìí,ṣùgbọ́n ọkàn mi wárìrì sí ọ̀rọ̀ Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:157-170