Sáàmù 119:147 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi dìde ṣáájú àfẹ̀mọ́júmọ́ èmi ké fún ìràn lọ́wọ́;èmi ti mú ìrètí mi sínú ọ̀rọ̀ Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:143-150