Sáàmù 119:132 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yí padà sí mi kí o sì ṣàánú fún mi,bí ìwọ ṣe máa ń ṣe nígbà gbogbo sí àwọntí ó fẹ́ràn orúkọ Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:122-137