Sáàmù 119:115 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin olùṣe búburú,kí èmi lè pa àṣẹ Ọlọ́run mi mọ́!

Sáàmù 119

Sáàmù 119:110-119