Sáàmù 119:104 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi rí òye gbà nínú ẹ̀kọ́ Rẹ;nítorí náà èmi kórìíra gbogbo ọ̀nà tí kò tọ́.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:100-108