Sáàmù 118:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún àwọn tí ó wá ní orúkọ Olúwa.Láti ilé Olúwa wá ní àwa fi ìbùkún fún ọ.

Sáàmù 118

Sáàmù 118:16-29