Sáàmù 118:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn gbá yìnìn yí mí ká bí oyin,ṣùgbọ́n wọ́n kú kíákíá bí iná ẹ̀gún;ní orúkọ Olúwa èmi ké wọn dànù.

Sáàmù 118

Sáàmù 118:6-13