Sáàmù 118:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa, nítorí tí ó dára;àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

2. Jẹ́ kí Ísírẹ́lì wí pé:“Àánú Rẹ̀ dúró láéláé”.

3. Jẹ́ kí ilé Árónì wí pé:“Àánú Rẹ̀ dúró láéláé”.

Sáàmù 118