Sáàmù 115:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ní etí, ṣùgbọ́n wọn kò gbọ́ràn:wọ́n ní imú, ṣùgbọ́n wọ́n kò fi gbóòórùn

Sáàmù 115

Sáàmù 115:1-10